Iforukosile ti odun 2023
Appearance
Outdated translations are marked like this.
16–19 August 2023, Singapore and Online
Diversity. Collaboration. Future.
Iforukosile fun wikimani ti odun 2023 ti si sile bayi. Foruko lati darapo ni Singapore tabi lori ero.
Ejowo ewo oro iforuko sile ti apamo.https://wikimania.wikimedia.org/wiki/wmf:Special:MyLanguage/Legal:Wikimania 2023 Registration Privacy Statement
Wikimania lati ojuero ati iforukosile funrarae ama sele ni ori igbekale to si sile https://eventyay.com/.
Ti eba gba eko ofe lati idasile wikimania tabi e ro mo wikimania, e ma gba email pelu itoni iforukosile.
Iforuko sile ti ara mase ipese ounje osan ni ojo kerindinlogun si ojo kokandinlogun; ounje ale ni ojo kerindinlogun ati ojo kokandinlogun ti osu kejo. Wifi ati socket ma wani ipesesile ni ibi Conference na.